[female vocals] Ta
ni
a
ba
fi
o
we
Ta
lo
le
ba
o
dogba
Olorun
agbalagba
Oba
adani
ma
gbagbe
eni
E
ku
ise
Jesu,
Iwo
ni
mo
fiba
fun
Iwo
ni
ohun
gbogbo
ninu
aye
mi
Oluranlowo
mi,
Onipese
mi
Iwo
ni
asà
mi,
Iwo
ni
ihamọra
mi
Olugbeja
mi
to
ga
julo
Oluwa,
o
seun,
o
dara
pupo
Oluwa,
o
kun
fun
inu
rere
Iwo
ni
iyanu,
Iwo
l'ẹni
giga
julo
Olorun
mi,
Iwo
j'eni
to
tayọ
ninu
oun
gbogbo
Oluwa,
o
kun
fun
inu
rere
Iwo
ni
iyanu,
Iwo
l'ẹni
giga
julo
Olorun
mi,
Iwo
j'eni
to
tayọ
ninu
oun
gbogbo
Jesu,
Iwo
ni
mo
fiba
fun
Iwo
ni
ohun
gbogbo
ninu
aye
mi
Oniwosan
mi,
Olumupada
mi
Iwo
ni
oluso
mi,
Iwo
ni
oludande
mi
Oluwa,
o
seun,
o
dara
pupo
Oluwa,
o
kun
fun
inu
rere
Iwo
ni
iyanu,
Iwo
l'ẹni
giga
julo
Olorun
mi,
Iwo
j'eni
to
tayọ
ninu
oun
gbogbo.
Eseun
Baba,
o
seun
Adupe,
a
juba
re
Olorun
mi,
o
ga
ju
aye
lo
Iwo
l'oba
awon
oba
Jesu,
Iwo
ni
mo
fiba
mi
fun
Iwo
ni
ohun
gbogbo
ninu
aye
mi
Iwo
ni
ayo
mi,
Iwo
ni
oniduro
mi
Olorun
to
s'aye
mi
dire
Oluwa,
o
seun,
o
dara
pupo
Oluwa,
o
kun
fun
inu
rere
Iwo
ni
iyanu,
Iwo
l'ẹni
to
giga
julo
Olorun
mi,
Iwo
j'eni
to
tayọ
ninu
oun
gbogbo
Oluwa,
o
seun,
o
dara
pupo
Oluwa,
o
kun
fun
inu
rere
Eseun
Baba,
Iwo
l'oni
agbara
Iwo
nikan
ni
ogo
ati
iyin
ye
fun