[female vocals] Oluwa
lo
da
ile
aye,
a
gbudo
toju
re
Eseun
Baba,
fun
ore
ofe
ti
e
fun
wa
Ile
aye
yi,
ebun
nla
lati
odo
Olorun
Oluwa
lo
mo
bi
o
se
da,
o
si
fun
wa
ni
abojuto
Sugbon
awa
omo
eniyan,
a
n
ba
ile
je
E
je
ki
a
sora,
ki
a
ma
da
idoti
si
gbogbo
ibi
E
je
ki
a
toju
aye
wa,
oju
a
ni
ba
wa
E
ma
da
idoti
si
oju
ona,
Olorun
n
wo
wa
Toju
ayika
re,
k’
ile
o
le
mo
rere
A
n
dupẹ
lọwọ
Ọlọrun
fun
ẹ̀
bùn
t’
Ó
fún
wa
Ninu
ile,
ninu
ita,
e
je
ki
a
gba
ibi
mo
Itoju
ayika
je
ise
rere
fun
Olorun
Bi
o
ba
jẹ
ṣiṣẹ,
kọ
kuro
lẹgbẹ
ọna
Oluwa
fe
ki
aye
wa
o
ma
dan
gbinrin
E
je
ki
a
toju
aye
wa,
oju
a
ni
ba
wa
E
ma
da
idoti
si
oju
ona,
Olorun
n
wo
wa
Toju
ayika
re,
k’
ile
o
le
mo
rere
A
n
dupẹ
lọwọ
Ọlọrun
fun
ẹ̀
bùn
t’
Ó
fún
wa
Olorun
ni
oniseda,
a
ni
lati
se
oju
se
Eseun
Baba,
fun
ogo
ti
e
fi
si
inu
ile
aye
Awa
yoo
toju
re,
awa
yoo
so
o
di
mimo
Eseun,
Eseun,
Eseun
Baba!
Ona
kan
pataki
ni
lati
ya
idoti
soto
Eyi
ti
o
le
bajẹ,
fi
si
ibi
to
tọ
Oluwa
yoo
bukun
ise
owo
wa
Ka
pa
ayika
wa
mo,
k’
aye
o
le
dun
wo
E
je
ki
a
toju
aye
wa,
oju
a
ni
ba
wa
E
ma
da
idoti
si
oju
ona,
Olorun
n
wo
wa
Toju
ayika
re,
k’
ile
o
le
mo
rere
Bi
o
ba
gba
ile
tan ,
ya
ike ,
pali,
gilasi,
irin,
si
oto
gedegbe,
Gbogbo
idoti
ti
o
ba
le
baje
bi
eso,
efo,
ounje
ajeku,
ati
bebelo
ko
eyi
naa
si
oto
gedegbe,
owo
kan
ni
eyi
naa
je,
fun
wa.
Ao
ni
lati
fun
owo
danu
mo,
ti
o
ba
le
se
ayan
idoti
re
ki
o
wa
ni
awon
ipele
yi,
Haa
owo
de
niyen,
Ni
ilu
Ikorodu,
Ati
Gbogbo
agbegbe
Idoti
ti
di
owo
ooo,
kiki
pe
ki
ti
pese
re
sile
fun
iyapada
si
Ohun
elo
bi
Gaasi
idana,
Ajile
fun
awon
agbe
wa,
Gbogbo
wa
ni
a
maa
laa
ti
a
ba
le
fi
anfaani
ti
o
wa
ninu
sise
itoju
ayika
ati
sise
ayan
idoti
si
ototo,
ki
a
maa
da
luru
pomo
saapa.
Ao
di
olowo,
ao
si
tun
ni
Alaafia
ti
o
peeye
nipa
sise
bee.
Ikeede
yi
wa
lati
odo
foundation
kan
ti
a
n
pe
ni
Nature
Friends
Humanitarian
Foundation.
Darapo
Mo
wa
ninu
olu
ile
ise
wa
ninu
ogba
yinufasi (
Lasustech)
ni
ilu
Ikorodu
fun
ekunrere
alaaye
lori
sise
ayan
idoti
ti
o
fi
di
owo
nla
fun
wa.
Toju
ayika
re,
ise
rere
ni
fun
Olorun
Gbogbo
wa
laa
ma
laaa