Frobits
🎵 A song made on Frobits

Iranti Iya Mi Abebi (Remix)

0:000:00
Download
Reply with a song
Lyrics

[male vocals] Iya

ni

wura,

Abebi

iya

mi

dada,

aya

Omo

oba

ni

ode

Osogbo

Oroki.

Awa

omo

re

n

ranti

re.

Iya

mi

Abebi,

aya

Buraimoh

Ajao,

omo

oba

ni

ode

Osogbo

Oroki.

Ejika

mi

tio

je

ki

ewu

ja

bo

titi

laye

ni

Mo

ma

se

iranti

yin

ni

ojo

riri

je,

ni

ojo

ayirije

Iya

mi

Abebi,

akodu

ki

ya

re

ta,

ki

Omo

kole

jeun

Omi

n

bo

ni

oju

mi

ni

ojo

ti

iya

mi

ku,

o

fi

mi

sile.

ofi

mi

si

le

lo

Abebi,

iya

mi

wura

mi,

mo

n

ranti

re.

Abebi,

iya

mi,

wura

mi,

mo

n

ranti

re.

Ki

ema

ba

mi

ki

baba

mi

buraimoh

OsunToyinbo,

e

sun

re

o,

sugbon

e

boju

wo

eyin.

wo

awa

Omo

re,

ki

ema

fiwa

sile

fun

iya

je

Mo

ranti

oro

isiti

ti

won

so

fun

mi.

Won

ni

omo

ti

ko

ba

dara

ni

iya

re

n

ku.

Eyi

ti

o

ba

dara

gbo

gbo

obinrin

aye

ni

iya

re.

Iya

mi

my

Gold

ti

money

can't

buy

nitori

iya

mi

se

owon

laarin

awon

iya

Abebi,

iya

mi,

wura

mi,

mo

n

ranti

re.

Abebi,

iya

mi,

wura

mi,

mo

n

ranti

re.

Buraimoh

OsunToyinbo,

e

sun

re

o,

sugbon

e

boju

wo

eyin.

Awa

omo

re

wa

n

dupe,

awa

omo

re

wa

n

ranti.

Ki

Olorun

oba

ki

o

ba

se

iku

ni

sinmi

fun

yin.

Abiyamo

to

to,

iya

to

mo

ise

omo.

E

sun

re

o,

aya

oba

ni

ode

Osogbo

Oroki.

Abebi,

omo

Buraimoh

Ajao,

e

sun

re

o.

Omi

oju

mi

n

san,

sugbon

mo

mo

pe

e

wa

ninu

alaafia.

OsunToyinbo,

iya

rere,

iya

oninure.

Awa

omo

re

ki

yio

gba

gbe

yin.

Iya

mi

Abebi,

mo

n

se

iranti

re.

Abebi,

iya

mi,

wura

mi,

mo

n

ranti

re.

Abebi,

iya

mi,

wura

mi,

mo

n

ranti

re.

B,

A

OsunToyinbo,

e

sun

re

o,

sugbon

e

boju

wo

eyin.

Wo

awa

Omo

yin

E

sun

re

o,

Abebi,

iya

mi.

E

boju

wo

eyin,

ki

e

ma

fi

awa

omo

re

sile.

Iya

mi,

e

sun

re

o.

Ire

o,

Abebi,

My

Gold!!!

More songs by Swagger Listen to songs created by others
FROBITS