[male vocals] Ikorodu
Oga!
Ise
wa ,
Owo
jabuarata,
Obinrin ,
Okunrin ,
Omode
ati
Odo
langba,
Ilu
Ikorodu
Oga
to
Gbogbo
wa
ni
Owo
n
be,
o
ya
akoko
ti
too
lati
se
amojuto
idoti
ni
ona
tio
yio
maa
mu
owo
wole
fun
Gbogbo
ni
Jaburata,
ti
ilu
Ikorodu
yio
si
mo
kedere,
sise
ayan
idoti
ni
oto
oto
ni
ona
ti
a
Fi
gba
maa
pa
owo
lati
ara
idoti
ti
a
ayika ,
oja,
ile
owe,
ile
ise ,
soosi ,
mosalasi
ati
Gbogbo
agbeegbe
waa
yio
fi
wa
ni
mimo ,
ti
o
si
maa
pa
owo
si
apo
wa
lati
ara
idoti.
Nature
friends
Humanitarian
foundation
ti
ile
ise
wa
wa
ni
ogba
Yunifasiti
Lasustech,
ti
ilu
Ikorodu,
ti
seetan
lati
so
owo
idoti
ti
a
sa
ti
otooto
di
owo
Jaburata
fun
waa.
Nylon
dudu
looto,
nylon
pure
water
looto,
ike
Omi
looto,
pali,
paper,
aso,
bata,
eso,
ewebe,
ata,
ati
Gbogbo
Ohun
ti
enu
nje
ti
o
ti
baje
looto,
ao
si
gbogbo
re
do
wo
fun
yin
ti
o
ba
ti
wa
ni
otooto.
ti
e
si
gbe
fun
awon
tio
ba
wa
sise
ti
yio
maa
wa
gba
lowo
yin.
E
je
ka
jump
size
rere
fun
ayika
ati
agbegbe
Ikorodu,
ki
oo
le
wa
ni
alaafia,
ni
mimo
toni
toni,
ki
Oro
wa
lee
posi
ni
ilu
Ikorodu.
Ikorodu
Oga,
Itesiwaju
ti
de
o,
nipa
bi
o
a
se
Ma
se
itoju
awon
idoti
wa.
ti
yio
fi
le
wulo
fun
ikan
miran
fun
wa
ti
yio
si
owo
Jaburata
fun
Gbogbo
wa.
Oju
ona
Ikorodu,
ile
ise
n
ru
A
n
sa
lo,
a
n
sa
bo,
k'owo
le
pe
Oju
ona
Ikorodu,
ile
ise
n
ru
A
n
sa
lo,
a
n
sa
bo,
k'owo
le
pe
Ko
si
ohun
ti
o
le
da
wa
duro
A
n
sise
takuntakun,
owo
n
wole
Ikorodu
o,
ilu
to
n
mu
ire
wa
Owo
n
be,
alafia
n
be,
ola
n
be
A
n
kojo,
a
n
toju,
ojo
ola
Ikorodu
l'awa,
a
n
se
bi
oba
Ikorodu,
mo
ni
owo,
mo
ni
alafia
Owo
n
be
ninu
apo,
ire
n
be
nile
Ikorodu,
mo
ni
owo,
mo
ni
alafia
Owo
n
be
ninu
apo,
ire
n
be
nile
Clean
Naija,
ibi
gbogbo
n
mọ
A
n
tọju
ilu
wa,
k'o
ma
dọti
Owo
n
wole,
ise
n
lọ,
ẹni
t'o
n
ṣiṣẹ
Ikorodu
la
gbe,
a
n
ṣe
bi
ọmọluabi
K'a
fi
mọto,
k'a
fi
ile,
k'a
fi
owo
Iṣẹ
l'ogun
iṣẹ,
ẹ
jẹ
k'a
ṣiṣẹ
Owo
n
bẹ,
owo
n
bẹ
l'owo
wa
Ikorodu
a
ni
owo,
a
n
gbadun
Ikorodu,
mo
ni
owo,
mo
ni
alafia
Owo
n
be
ninu
apo,
ire
n
be
nile
Ikorodu,
mo
ni
owo,
mo
ni
alafia
Owo
n
be
ninu
apo,
ire
n
be
nile
Iṣẹ
lo
mọ,
owo
l'o
n
bẹ
Ko
si
wahala,
iṣẹ
wa
l'o
n
ṣe
A
n
toju
ilu
wa,
Clean
Naija
l'o
ye
wa
Owo
n
bẹ,
ayọ
n
bẹ,
o
d'ọla
Ona
kan
o
wọ
ọja,
ọna
pọ
l'a
n
gba
Ikorodu
kọ,
iṣẹ
n
bẹ,
owo
n
bẹ
Ẹ
k'a
ṣe,
ẹ
k'a
jẹ,
ẹ
k'a
mu
Owo
n
bẹ
ninu
apo,
owo
n
bẹ
l'ọwọ
Ikorodu
n
ṣaaju,
iṣẹ
n
lọ
bi
epo
Ẹ
jẹ
k'a
gbadun,
owo
n
bẹ,
owo
n
bẹ
Ikorodu,
mo
ni
owo,
mo
ni
alafia
Owo
n
be
ninu
apo,
ire
n
be
nile
Ikorodu,
mo
ni
owo,
mo
ni
alafia
Owo
n
be
ninu
apo,
ire
n
be
nile
Ikorodu
mo
ni
owo,
owo
n
bẹ
Clean
Naija,
iṣẹ
n
lọ,
owo
n
bẹ
Ikorodu
o,
owo
n
bẹ
l'ọwọ
Ire
n
bẹ,
alafia
n
bẹ